We Dream of... Lakes and Forests of Ontario, Canada

ÕRÕ ÌKÍNI KÁÀBÕ

A ní ìrètí pé ç óò rí i pé àwôn ilé-ìwòsàn wa àti aáyan ìwadìí wa tí a gbé kalê sórí ìkóríta yìí yóò fún yin ní ìmõ pipe tí ó sì wúni lórí. Àwôn nýkan àbùdá aláìlëgbë púpõ nípa irúkan-õkan àrùn ômödé wà níbê. Nínú wôn ni a óò rí àwôn ìwé êkö ìfisùn nípa ìmõràn tí ó tö fún çnìkõõkan àti ti çlëgbëjçgbë. A tçnumö ÿíÿe aáyan ìwadìí gidigidi, à sì tún töka sí àwôn ìwé ìranra-çni-löwö tí ó wà lórí ìkóríta yìí. Àwôn òÿìÿë wa wá láti onírúurú ìÿêÿe, wön sì þ sô oríÿìíríÿìí èdè ìbílê tí ó lé ní ogún. Púpõ nínú wôn ni ó gba oyè dókítà láti orílê-èdè mìíràn tí wôn sì ti ÿiÿë ní êka iÿë ìmõ nípa oorun fún õpõlôpõ ôdún. Wôn ní ìmõ tí ó péye nínú êka iÿë yìí. A gbàgbö pé èyí fikún àwòmö ètò iÿë wa.

Ó jë ohun ìyanu pé díê lásan ni a mõ nípa oorun àti àwôn nýkan tí ó þ fa àìÿedéédé rê àti bí ó ÿe jë pé àÿàrò nípa êka ìÿë yìí ÿêÿê bêrê láìpë yìí ni. Nítorí ìdí èyì, ìlôsíwájú kankan þyára dé sí êka ìmõ yìí. A ní ìrètí pé ç óò máa fi ìkóríta wa sökàn láti ìgbà dé ìgbà tí ç bá þ wá ìmõ titun lórí iÿë yìí.

Õkan nínú àwôn nýkan àbùdá wa ni ìwé ìròhìn pçlçbç tí a þ tê jade ní oÿù mëta-mëta. A ní ìrètí pé ç óò rí àwôn àwòrán tí ó fanimöra tí ó sì múni ronú jinlê lori ìkóríta yìí. Wön jë ohun ìrántí orílê-èdè ìbílê àwôn òÿìÿë wa tí ó sì þ mù wôn ÿe ìdárò ilé.

Ire o.
Õjõgbön Colin Shapiro, Bsc, MBBCh, PhD, MRCPsych, FRCP(C)
Êka Ìmõ Àrùn Ôpôlô
Yunifásítì ìlú Toronto

ÕRÕ NÍPA ISË PÀTÀKÌ YÌÍ

Ìmõ ìjìnlê-èrò nípa àwôn ilé ìwòsàn wa àti aáyan ìwadìí àìsàn tí a þ ÿe ni láti pèsè ìtöjú tí ó péye fún gbogbo ènìyàn tí ó þ ÿòro fún làti sùn tàbí kí wôn wà láìsùn pêlú ìlera. Tômôdé-tàgbà ni ètò yìí wà fún. A þ gbìyànjú láti máa wá àwôn õnà titun tí ó sì dára jùlô láti ÿe ìtöjú yìí ní àbálé-àbálé. Ohun tí a tçjúmö ni làti ÿe ìwadìí àwôn ìÿòro tí aláìsàn ní kí a sì fi èrèdì àìsàn nàá hàn. Ètò aáyan ìwadìí õràn àti ìmõ ìtöjú aláìsàn ni àpapõ ni a þ lò làti fi yanjú ìÿòro tí aláìsàn ní.

See Our Clinic's Video Tour

Art and Sleep

 
© 2010 - 2024 Toronto Sleep Clinics, Ontario Sleep Clinics. All rights reserved.